Se be e ri oga Jona to dore omo Abacha

Transkript

Se be e ri oga Jona to dore omo Abacha
E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Se be e ri oga Jona to dore omo Abacha
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
Mo ti fegbe sile fun
Bi olori ijoôba kan ba nilaari, to si jeô eôni apoônle to jeô eôni iyi funra reô, to ni itiju, to si moô ohun
to n sôe, bi ko ba ri eeyan kan ba a rin laye moô ni Naijiria yii, sôe oômoô Sani Abacha ni yoo waa
soô di oôreô imuleô ti woôn yoo joô maa woôle, ti woôn yoo joô maa jade. Nitori ki Jonathan sôaa tun le
di aareô leôeôkeji yii, oômoô Abacha lo ku to n ba sôoôreô o. Titi di bi a sôe n wi yii, woôn ko ti i gba
owo ti Abacha ji ko pamoô soke-okun tan, ojoojumoô ni awoôn ti woôn ko owo naa si loôdoô n fi
oni donii ti woôn n fi oôla doôla, awoôn mi-in si n soô pe awoôn ko tileô moô ibi ti owo naa wa moô
rara. Bakan naa ni awoôn mi-in n wa awoôn oômoô Abacha yii lati ba woôn sôeôjoô, nitori woôn ni
orukoô woôn ni baba woôn wa fi ko owo naa pamoô, beôeô ni awoôn naa waa ko awoôn owo kan
pamoô nibeô funra woôn. Nigba ti eleyii ba waa ri beôeô, sôe o waa yeô ko jeô awoôn oôta ilu bayii ni
Jonathan yoo soô di oôreô bi! Bo ba sôe pe nibi ti ijoôba ti dara ni, to ba sôe nibi ti woôn ti n sôe ohun
gbogbo letoleto, iru awoôn oômoô Abacha ti woôn ji owo ko loô sibi kan yii yoo wa leôwoôn, bi
woôn ba si ti jade leôwoôn, ibi ti woôn yoo fi woôn si, eônu woôn ko ni i toôroô nibi kan. Sôugboôn ki la
n ri laye Jonathan, awoôn oômoô ti baba woôn fi ogun ja ilu yii, awoôn lo ku toun naa n ba sôoôreô,
awoôn lo ku to mu ni oludamoôran gidi. Gbogbo awoôn oniroyin lo gbe e pe Jonathan ati oômoô
Abacha n sôepade pataki nile ijoôba. Arifin buruku, oôroô rirun, eôgbin oniyoôroô, gbogbo nnkan si
dorikodo laye awoôn eeyan ti woôn ko moô kinni kan. Bi Jonathan ba tun woôle leôeôkeji bo sôe n
soô pe oun feôeô woôle, sôebi awoôn ojulowo oôreô reô naa niwoônyi, iyeôn a waa tumoô si pe kekere ni
iya to n jeô Naijiria lasiko yii, eyi ti yoo sôeôleô lati oôdun to n boô bo ba jeô oôkunrin to n pariwo
kiri pe baba oun ko rowo ra bata foun nigba kan yii naa lo ba tun woôle yoo buru pupoô ju
ohun ti eônikeôni ti ri loô. Ohun to han gbangba ni pe ijoôba yii ti dorikodo moô Jonathan loôwoô,
gbogbo eôni to ba si feôran Naijiria, ki woôn soô pe ko maa loô ni.
Amosun o, SDP lemi
naa ti fee dupo
Gomina—Igbakeji
Gomina
Nitori ti ko ri kaadi
alalope re gba, Fashola
ni INEC o sise won bii
ise
Ajimobi ko nilo
ipolongo ibo fodun
2015
Emmanuel fi majele
sinu ounje ayalegbe
egbe e n'Ilorin
Ibo abele da nnkan ru
ninu egbe APC ati PDP
nipinle Ogun
Oro beyin yo ninu egbe
PDP l'Ondo, alaga kowe
fipo sile
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa

Benzer belgeler

Wahala niluu Etire: Won ni Kabiyesi ran agbanipa sawon ti

Wahala niluu Etire: Won ni Kabiyesi ran agbanipa sawon ti E ba wa dele E mo nipa wa ba wa sise Adiresi wa

Detaylı

Awon Baale Oke Pata, niluu Ifo so pe Olu Ifo fee da ogun

Awon Baale Oke Pata, niluu Ifo so pe Olu Ifo fee da ogun •Egbe awon baale nijoba ibile Ifo O·ba Atanda tun soô pe,“Awa meôrin la pin ipo O·ba Olu Ifoô laarin ara wa, awa naa ni: Ake, Oke-O·na, Gbagura ati Owu. A ki i loôoô foribaleô fun oôba kankan ka to...

Detaylı