Awon Baale Oke Pata, niluu Ifo so pe Olu Ifo fee da ogun

Transkript

Awon Baale Oke Pata, niluu Ifo so pe Olu Ifo fee da ogun
E ba wa dele
E mo nipa wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Bi o ba fe ba wa sise
Adiresi wa
Awon Iroyin to se koko
Awon Baale Oke Pata, niluu Ifo so pe Olu Ifo fee da ogun sile niluu
awon
Nitori Ibo Gomina
2015, wahala be sile
Johnson Akinpelu, Abeokuta
laarin awon Yewa
O·loôrun oôba nikan lo le yanju aawoô to n sôeôleô laarin awoôn
kan ti woôn pe ara woôn ni Baaleô ni Oke Pata, ti woôn si soô pe
asôoju O·sôileô, iyeôn O·ba Adedapoô Teôjuosôo, lawoôn jeô, ati ti Olu
Ifoô tilu Ifoô, O·ba Samuel Atanda O·ladipupoô. O·roô naa ti di
egbinrin oôteô, bi woôn sôe n pa kan ni omin tun n ru.
Laipeô yii ni awoôn ti woôn pe ara woôn ni Baaleô naa pe oniroyin
wa, woôn feôsun kan Olu Ifoô pe o n koôja aaye eô, woôn ni o feôeô da
wahala sileô peôlu bo sôe n fi awoôn baaleô tuntun jeô l’Oke Pata
leôyin ti O·sôileô tawoôn moô pe o leôtoôoô lati fi ni joye ti fi awoôn jeô
Baaleô.
•Olu Ifo, Oba Samuel
Awoôn Baaleô ti woôn parapoô fimoô sôoôkan naa ni: Oloye Samuel
Atanda Oladipupo
Adio O·moôsanya Sôodiya, Baaleô Orile Ogun, Oloye O·badara
Bamgboye, Baaleô O·basa, Oloye Taofeek O·lawale Fasôina, Baaleô Osoosun, Oloye Samuel
Kayoôde Oloyede, Baaleô Osoosun tuntun, Baaleô David Ayoôoôla, Baaleô Sôoyinka Alaja ati
Oloye Sôotayoô Sôodeôhinde Sôoluade to jeô alaga awoôn Baale ni Oke Pata.
Awoôn Baaleô woônyi soô pe oôroô Olu Ifoô da bii afibisôu-oloore to feôeô maa fi oju oloore eô gungi.
Woôn ni ko si O·ba to jeô n’Ifoô to di Oke Pata loôwoô nitori gbogbo woôn lo moô pe oôdoô O·sôileô ni
woôn ti wa. Woôn ni O·ba Samuel Atanda gan-an, O·ba Oke O·na lo fi i joôba.
Woôn ni awoôn igun meôrin to ni ileô Eôgba, iyeôn Ake, Owu, Agura ati Oke O·na ni woôn maa n
pin oye O·ba Olu Ifoô naa, igba to kan Oke O·na ni woôn fi O·ba O·ladipupoô joye. Woôn ni nigba
ti O·ba naa koôkoô dori oye, o sôe daadaa, gbogbo nnkan to ba si feôeô sôe lo maa n loôoô gbasôeô reô
loôdoô Oôsôileô, sôugboôn biri lo deede yi, to waa deôni ti ko feôeô ba Oke O·na sôe moô.
Ninu oôroô Baaleô Samuel Adio O·moôsanya to jeô Baaleô Orile Ogun l’Oke Pata, o soô oô di mimoô
pe O·ba O·ladipupoô koô lo koôkoô jeô n’Ifoô, awoôn to si jeô sôiwaju reô ki i koôja aaye woôn, nitori woôn
ti moô pe O·sôileô lo ni oôdoô awoôn, asôeô to ba si ti pa naa lo gboôdoô muleô.
Baaleô Orile Ogun yii sôalaye pe,“Eô wo o, oôroô Olu Ifoô ti su gbogbo wa, ataleô jeôun ni. Mo ti
pe e leôjoô, oôroô naa si wa ni kootu, ko seôni ti ko le fi jeô Baaleô, yala eôni naa jeô oômoô ilu tabi ajoji,
ti woôn ba sôaa ti fun un ni eôgbeôrun loôna igba ataaboô to si tun gba odidi eôran ati oôti, onitoôhun ti
di Baaleô niyeôn, eyi ko si toôna.
“O tieô ti soô nigba kan ri pe oun naa ta ileô oun to wa l’Ekoo ko too di pe oun depo oôba ni,
nitori naa, tita loye Baaleô loôdoô oun. Adura wa ni pe ko ma da Eôgba ru, nitori nigba ti
Amosun pari ija awoôn oôba alaye meôrin niluu Eôgba, inu gbogbo wa lo dun, eô joôoô, eô ba wa beô
Olu Ifoô to n koôja aaye eô ko so agbejeô moôwoô o.’’
Nigba ti Baaleô O·bara Bamgboye ti O·basa n soôroô ni tieô, o ni ija lo de lorin dowe laarin oun ati
O·ba O·ladipupoô, ati pe nitori koun le maa ba Olu Ifoô taleô kaakiri lo sôe foun jeô asôoju eô, to si
foun niwee-eôri. O ni gbogbo igba toun ba si ti ta ileô loun maa loôoô fun un ni owo nile, igba
mi-in eôgbeôrun loôna igba naira tabi ju beôeô loô. Sôugboôn nigba toun ko fun un lowo moô, nisôe lo n
pariwo pe Baaleô ataleô loun, o ni ki woôn beere loôwoô Olu Ifoô boya ki i gba eôtoô eô nigba yeôn ati
pe ko dara ki O·ba naa waa maa pe oun ni Baaleô buruku bayii.
Sôaaju asikoô yii ni oloye kan ti woôn n pe ni Ajiroôba ti koôkoô soô pe oômoô ale eeyan lo le koôroô si
Olu Ifoô leônu ati pe ti oôba naa loun n sôe loôjoôkoôjoô, eyi lo mu Baaleô Bamgbosôe soô pe ateônujeô lo
n pa a ku loô nitori ohun to n jeô labeô oôba naa lo sôe n soô isoôkusoô beôeô. O ni iyaleônu lo jeô nigba ti
Awori
Awa la fi Folasade je
Iyaloja, o te wa lorun ni
Bombu l’Akure: Awon
odaran ju bombu sogba
ewon Olokuta
Eemo l’Ondo, alaga
awako, NURTW, ji
ewure gbe
O ma se o! Awon
oloselu yinbon pa
Kunle l’Edunabon
Lasiko eto imototo,
awon asewo lu olopaa
lalubami l’Akure
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa
woôn loôoô ko awoôn oômoô Owu wa lati waa da si oôroô ilu awoôn, awoôn ti Ajiroôba si ko wa loôjoô naa ki i sôoômoô Oke
Pata, o ni to ba joô bii iroô ki woôn boô sita.
Baaleô Samuel Kayoôde to wa lati Osoosun tuntun naa sôalaye pe nitori oun ba O·sôileô sôe poô, to si jeô pe oôdoô eô
lawoôn ti wa, nisôe ni Olu Ifoô ni ki woôn da oun duro, Iyeôn nikan koô, o tun loun yoo yan Baaleô meje niluu naa
ninu eyi ti alawo, onifa, onisôeôgun yoo wa ninu woôn. Baaleô yii soô pe idi ti Olu Ifoô sôe feôeô sôe eyi ni kawoôn
eeyan naa le maa sa si ara woôn, ki woôn si maa ku danu, ki aaye le wa lati tun fi awoôn mi-in jeô Baaleô tuntun
peôlu isôakoôleô tuntun. O ni loootoô O·ba naa yan Baaleô meôjoô loôjoô kan, koda oloye abeô oun tun wa lara awoôn to
soô di Baaleô, gbogbo ohun ti Oôba O·ladipupoô si n sôe yii ko dara. O fi kun un pe eôri wa lati fi gbe gbigbo ohun
to soô yii leôseô.
Geôgeô bi owe agba to ni a gboô eôjoô eôni kan
da agba osôika ni, ki awa ma baa jeô beôeô ni
akoôroyin wa sôe wa Olu Ifoô, O·ba Samuel
Atanda O·ladipupoô, loôoô saafin reô lati gboô
teônu oôba naa.
Kabiyesi naa sôalaye pe ni gbogbo igba ti
wahala oôba ti Olowu yan nigba kan fi beô
sileô, oun ri i pe oôroô naa ko fa itajeôsileô
rara, Olowu si yan O·ba kan si oôdoô awoôn
naa, ibi tawoôn to n pariwo yii ti waa ri
awoôn nnkan ti ko sôeôleô ti woôn soô naa ko
ye oun.
•Egbe awon baale nijoba ibile Ifo
O·ba Atanda tun soô pe,“Awa meôrin la pin
ipo O·ba Olu Ifoô laarin ara wa, awa naa ni: Ake, Oke-O·na, Gbagura ati Owu. A ki i loôoô foribaleô fun oôba
kankan ka too foôba jeô, a maa n pin in laarin ara wa ni.
Afoôbajeô marun-un la ni n’Ifoô, awoôn lo maa n sôisôeô lori eôni ti yoo joye, awoôn naa si ni Balogun, Jagunmolu
lati Ake, O·tun lati Oke O·na, Osi lati Gbagura ati Eôkeôrin lati Owu. Awoôn woônyi ni woôn yoo sôisôeô poô peôlu
awoôn oloye lati fi eôni to ba kan joôba.”
Lati aye Lipede ni woôn ti beôreô oôteô l’Abeôokuta, awa ko si feô ki woôn ko oôteô woôn de Ifoô nibi, Ifeô la n polongo
pe ko joôba laarin awoôn eeyan. Eô wo o, onigbagboô ni mi, nisôe lo maa n ni mi lara lati ki O·sôileô nitori oun ganan lo n da wahala sileô to si n yan mi lodi, eôni to pe ara eô ni ojisôeô O·loôrun, ki i wadii oôroô, nnkan tawoôn to n da
nnkan ru ba soô fun un lo n gboô.≈
Olu Ifoô tun soô pe loôjoô toun ti koôle tuntun toun n gbe ni wahala ti beôreô laarin oun ati O·sôileô, “Mo loôoô ba a
leôeômeji pe ko waa gbadura sile naa, titi dakoko yii, ko wa. Alake ti wa, Olowu ti wa, woôn ti sôadura fun mi,
kin ni ka ti gboô pe eôni to jeô O·ba O·sôileô ni ko wa, ko si si nnkan to ba feôeô sôe ti mi o ki i loô, eôni to n pe ara reô ni
ajihinrere ni ko wa.
“Meloo lawoôn ti woôn n pe ara woôn ni Baaleô naa, woôn ki i sôe Baaleô rara, woôn kan feôeô da ilu ru ni, O·loôrun ko
si ni i gba fun woôn. Eyi to pe ara eô ni Baaleô Osoosun to n pariwo, oômoô Ijaye ni, awoôn araalu eô si soô pawoôn
ko feô eô, loôjoô ti woôn feôeô fi i jeô Baaleô tipatipa, awoôn oôdoô ilu naa ya loô sibeô, woôn le awoôn oloye O·sôileô woôgbo,
woôn si gbe oôpa asôeô loô. Bi mo sôe gboô ni mo loô si tesôan awoôn oôloôpaa pe ki woôn da oôpa asôeô O·sôileô pada, nitori
oôpa asôeô koô ni woôn ji gbe, O·sôileô ni. Ki waa ni temi nibeô, bawo ni mo sôe le ni ki woôn loôoô da a ru, ibi teeyan ko
si O·loôrun wa nibeô.
“Eyi to si soô pe mo foun niwee eôri pe koun maa taleô, eô joôoô, eô ni ko mu iwe eôri naa jade, emi to jeô pe ariwo ti
mo maa n pa fawoôn Baaleô to wa labeô mi ni pe ki woôn ma ba woôn loôwoô si oôroô ileô, eônikeôni toôwoô ba teô yoo jeô
iyan reô nisôu, bawo waa ni mo sôe le ni ko maa taleô. Koda oôkan lara awoôn Baaleô to huwa yii ti asôiri reô si tu,
woôn ti da a duro nipo Baaleô to wa. Ohun to waa ya mi leônu nipa eôni teô eô n soô yii ni pe laipeô yii lo wa saafin
mi to waa beôbeô, loôjoô naa, o fun awoôn oloye ni eôgbeôrun meji naira, sôeô eô ri i pe ko moô nnkan to n soô.’’
Lori Ayoôoôla Sôoyinka to pe ara eô ni Baaleô, Olu Ifoô soô pe oôkunrin naa ki i gbe ni Alaja, Abeôokuta lo n gbe, beôeô
si ni ile iya iya eô ti woôn koô sibeô ti wo. O ni bawo leôni ti ki i gbe ilu sôe le waa feôeô joye le awoôn oômoô oniluu
lori. Bakan lo lo akoko naa lati soô fawoôn to n wa lati Abeôokuta ti woôn feôeô maa da wahala sileô n’Ifoô pe ki woôn
so agbejeô moôwoô, nitori inu ifeô ati ireôpoô lawoôn oômoô Eôgba to wa niluu naa n gbe

Benzer belgeler

Se be e ri oga Jona to dore omo Abacha

Se be e ri oga Jona to dore omo Abacha to n sôe, bi ko ba ri eeyan kan ba a rin laye moô ni Naijiria yii, sôe oômoô Sani Abacha ni yoo waa soô di oôreô imuleô ti woôn yoo joô maa woôle, ti woôn yoo joô maa jade. Nitori ki Jonathan sôaa ...

Detaylı

Wahala niluu Etire: Won ni Kabiyesi ran agbanipa sawon ti

Wahala niluu Etire: Won ni Kabiyesi ran agbanipa sawon ti Gege bo sôe soô, “O yeô ka loô si kootu lori eôjoô to wa lori oôroô ileô ti a n ja si yeôn loôjoô keje, osôu karun-un, oôdun yii, sôugboôn nigba ti oôjoô to yeô ka loô si kootu ku oôtunla, iyeôn lo...

Detaylı